ASMN Ogun State Headquarter

ASMN Ogun State Headquarter AGBEKOYA SOLIDARITY MOVEMENT OF NIGERIA
Motto: ILE YIO GBE WA

NATIONAL HEADQUARTER: Olorunda Ogunso

08/10/2024
09/03/2024

We celebrate your victory Anthony Joshua

Èyíinì iṣẹlẹ abàmì àti kayeefi ńláǹlà tí ó sele ni ilu Olodo ijoba ibile Odeda. Ọmọbìnrin tí an wo nínú agbára ẹ̀jẹ̀ ni...
26/02/2024

Èyíinì iṣẹlẹ abàmì àti kayeefi ńláǹlà tí ó sele ni ilu Olodo ijoba ibile Odeda. Ọmọbìnrin tí an wo nínú agbára ẹ̀jẹ̀ ni àwọn onise láabi lupa mo le nínú ìyẹ̀wù tí wọn sì fọ lórí yáná yáná.
Èyíi mú kí àwọn ènìyàn ara àdúgbò pẹ̀lú ìyá ọmọbìnrin yí bugbe tá nígbà tí ìyà ọmọbìnrin yìí ṣe alaba pàdé ọmọkùnrin kan nínú igbó leba ilé tí ó sì jẹ wípé ẹni tí ó sún mọ́ ọmọbìnrin tí ó kú yìí daradara.
Èyíi mú kí àwọn ará ìlú pè eso alabo agbekoya Solidarity Movement of Nigeria lati wa fún iwadi òtítọ́ àti òdodo. Agbekoya àti àwọn dijo pàdé nibẹ tí wọn gbé òkú ọmọbìnrin yí lọ sí ilé igbokusi tí a fura si yí sii mbẹ ni ahamo àwọn olopa. Ìwádìí sí tẹ síwájú...
This is unbelievable incident that happened in a town called Olodo in Odeda Local government area.
A lady named Tope was gruesomely killed by a suspected boyfriend boyfriend.
This incident happened yesterday Sunday 26th of February 2024.
The suspect has been arrested in collaboration with police and he is in police custody also the deceased has been taken to the mortuary. Investigation is still on going.......

Address

All The Local Govt Area Of
Abeokuta

Telephone

+2348038548351

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ASMN Ogun State Headquarter posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to ASMN Ogun State Headquarter:

Share