Adéjokéewàèdèadúláwò

Adéjokéewàèdèadúláwò African arts revitalization platform
(2)

25/05/2026

Trust nobody, ìfura ni òògùn àgbà, a ò níí rin àrìn f'e̩sè̩sí t'o̩mọ t'ọmọ o. Àṣẹ o

22/05/2026

Èrò kìí dára kí iṣẹ́ bàjé̩.
Betrayal may hurt me, but it will never redefine me.

20/05/2026

Purity at its peak🧑‍🎤



WhatsApp messages only. No DM please

18/05/2026

Ẹni t'ó mọ ọjó̩ òwò, yíò mọ ọjó̩ ikú.
Dreams don’t work on a schedule, they do on persistence.Sometimes it feels pointless, when progress is invisible, when quitting sounds reasonable, these are usually the moments that separates people who wish from people who become.Keep going anyway, every small steps counts. Ire o!

11/05/2026

That Delay may be a blessing in disguise. Adánidúró n d’áni dúró de olóore ẹni.

11/05/2026

That Delay may be a blessing in disguise. Adánidúró n d’áni dúró de olóore ẹni.

04/05/2026

Oun tí ojú akọnní rí t'ó fi sọ ọ̀pá nù l'ájò, b'óbá ṣe ò̩lẹ ni, ọ̀lẹ á ti dé ilí t'ipé̩. Please do all you can to stay ALIVE. Ire o

01/05/2026

Èbìbí bi ikú, èbìbí bi àrùn, nínú oṣù èbìbí yìí, ojú rẹ ò níí rí ibi l'áṣẹ èdùmàrè 🙏

Address

Gbàgede ẸwàÈdè Cultural Centre, Off Nigerian Customs Office, Quarry Road
Abeokuta

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Adéjokéewàèdèadúláwò posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Adéjokéewàèdèadúláwò:

Share

Category