25/09/2025
AKOLE ISE >>> ISE AANU (Part 1)
INKAN ELO RE >> EWE OBI TUTU TABI GBIGBE. EEPO EERUN. LOFINDA BINTU IGO KAN. OSE.
SISE RE >> AO GUN AWON INKAN ELO YII PAPO DAADA. AO WAA POO PAPO MON OSE. AO KO OSE NAA SINU IGBA OLOMORI.
LILO RE>> WIWE LEYIN IJO KETA. ( After 3days)
NOTE:: ISE YII DARA PUPO. KO SEE FOJU DII Ooooooo!!!
Lati owo ALASE ATI OLUDASILE EGBE FOTITO JAWE & ARAGBE LAYE GROUPS. Doctor Olaiya Aremu, (RIDDOH LLAHI)