Asiri aye

Asiri aye ASIRI TI EYAN FI GBA ISE KEKERE OWO NLA.. GBOGBO EYAN PATAPATA NI ISE YI WULO FUN TOFI DE ORI OMO Yahoo

IRU AISAN WO LO DAMU RE?IRU ISORO ATI OGUN WO LO DOJUKO?KO SINU COMMENT ABI KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP 09029903746
07/06/2025

IRU AISAN WO LO DAMU RE?

IRU ISORO ATI OGUN WO LO DOJUKO?

KO SINU COMMENT ABI KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP 09029903746

MOKOTOBI MOKOGUN TODAJUTia ban soro nipa mokogun mokotobi,ise mokogun yi ko jami ni tanmon ri,opolopo lo ti dagba sugbon...
28/10/2024

MOKOTOBI MOKOGUN TODAJU

Tia ban soro nipa mokogun mokotobi,ise mokogun yi ko jami ni tanmon ri,opolopo lo ti dagba sugbon oko e ko ju bi tomodun marun lo,dan ise mokogun yi wo kio dupe


(1)ORI ATI IRU ALANGBA MEJI
(2)ESO OPAPARA
(3)OSE DUDU
(4)SUKU AGBADO TOTOBI

:
AO GUN ORI ATI IRU ALANGBA MEJEEJI YEN PAPO MON ESO OPAPARA,AO POMO OSE DUDU,AO WA LE MON ARA SULU AGBADO TOTOBI

:
AO MA FI FO NKAN OMOKUNRIN WA WA SIWAJU,YIO GUN,YIO SI TOBI,YIO SI LE DAADA...

MAA FI EBU RE SILE LAIPE...

FUN IBERE -09053578036

EYI TIA TI SE SILE WA FUN TITA

Which sickness I you face inCantantSongun songun awoka ati lakure gbe (1) otutu igba aya (2) Arun oju (3) ito suger (4) ...
04/09/2024

Which sickness I you face in
Cantant
Songun songun awoka ati lakure gbe (1) otutu igba aya (2) Arun oju (3) ito suger (4) ayadidun (5) iko ife (6) obinrin oloyun ti iba walarea (8) eni to oba sanraju to ofe dinku (9) egbo (10) ogun oru inu obirin (11) eto ibalopo ti kosi oyun (12) ogun isoye (13) omo ikoko to olemidada (13) ogun Jedi inu (14) ako iba (15) ogun atole call me to this number 09029903746

OGUN IDAKOLE, ALEKO Egbo awogba arun, egbo oguno, egbo madunmaro, egbo ogbo, egbo ose, egbo orogbo, egbo grofa, egbo gbo...
21/08/2024

OGUN IDAKOLE, ALEKO
Egbo awogba arun, egbo oguno, egbo madunmaro, egbo ogbo, egbo ose, egbo orogbo, egbo grofa, egbo gbogbo nse, rire lomi, ao ma mu leemeji lojumo

Sugbon ki a to mu ogun yi, a o maa je mesenmesen oojo lenu, a o wa mu ogun yi le lori

FUN IBERE PEMI SORI NUMBER MI 09029903746TABI WHATSAPP NUMBER 09029903746

OGUN IDAKOLE OKUNRIN TODAJU Odidi Bara kan , Ao yo gbogbo koro inu re danu .Ao o ge kekeke , Ogede Agbagba dudu kan, Ao ...
29/07/2024

OGUN IDAKOLE OKUNRIN TODAJU

Odidi Bara kan , Ao yo gbogbo koro inu re danu .
Ao o ge kekeke , Ogede Agbagba dudu kan, Ao bi epo ara re kuro , Ao o ge kekeke , Ireke Ibile Kan, Ao o ge kekeke , Egbo Sapo , Ao o ge kekeke, Kafura pelebe die.
Ao o fi Oti Ogogo re awon Eroja yen fun ojo meta (3 Days). Ao o ma mu Cup kekere kan laaro ati lale ,emeji lojumo (Twice in a Day)

Fun gbogbo Iwo ti oba ni ido juko Lori

*Airi oyun ni

*Inkan omo okunrin tokere koja ojo Ori

*Ogun Eda

*Fun iwo ti ona dimo

*Abi were

*Fun iwo ti Oni idoku ko Lori oko abi iyawo

* Lori ISE re tikolo Dede

Lori oun ko oun ti oba ni idoku ko le Lori pemi si Ori number 09029903746
Or what's app 09029903746

NoMOKOTOBI MOKOGUN TODAJUTia ban soro nipa mokogun mokotobi,ise mokogun yi ko jami ni tanmon ri,opolopo lo ti dagba sugb...
16/07/2024

NoMOKOTOBI MOKOGUN TODAJU
Tia ban soro nipa mokogun mokotobi,ise mokogun yi ko jami ni tanmon ri,opolopo lo ti dagba sugbon oko e ko ju bi tomodun marun lo,dan ise mokogun yi wo kio dupe
EROJA
Pandoro nla kan
Odidi Atare kan
Ori
Ose dudu...
SISERE
Ao ge ori ati idi pandoro yen,ao gun mo odidi atare kan ti yio kuna daada,ao wa da simeji,ao po idakan mose dudu,ao po idakeji mon ori...
LILORE
Ao ma fi ose yen fo oko wa siwaju,ao ma fi ori yen pa siwaju lehin ti a ti fo ose yen kuro,oko okun yio gun,yio si tobi,yio si le sise daada
Fun ibere ati lati ra eyi ti a ti se sile-09029903746abi WhatsApp

AGBO FUN GBOGBO NISE. IDAKOLE EDAATOSINFIBROIDITO SUGAIFONU FUN OMO BIBIATI BEBELO..EJE KAFI ASIRI YI WA ALAFIA FUN AGO ...
16/07/2024

AGBO FUN GBOGBO NISE.

IDAKOLE
EDA
ATOSIN
FIBROID
ITO SUGA
IFONU FUN OMO BIBI
ATI BEBELO..

EJE KAFI ASIRI YI WA ALAFIA FUN AGO ARAWA

MOTI FI ASIRI YII SILE NINU ILE YI RI, TI OPOLOPO AWON ENIYAN SIN DUPE FUN OLOHUN OBA LARA RE..

IWO NA DANWO KOFUN ILE LABOO

ISENA RE:-
Ao bo epo ogede agba gba tiko pon ao wa ge ogede yi kekeke sinu ike kan ao wa ko ata ijosi si ao bu omi si ao de mole fun ojo meta leyin ojo keta ao wa fi a*o ise ogi tabi ase, se ao wa Sese ro omi re si ibi kan odi mimu kosi iru aisan ti kowo ao mamun ni gas kan laro lale fun Oni ruru aisan, confirmed nii oo.. Tio bafe ki asiri yi sise fun oo daadaa koko share re si opolopo group, kio si fi comment re se adura fun mi kio to dawo le...

ENITI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MA BI O FESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09029903746)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE..

FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09029903746)) TIO BANI IGBAGBO

LATI OWO OLUDASILE YARA IRANLOWO NIPA LILO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN ATI FUN ONA ABAYO

FOLLOW MI LATI JE AWON ORISIRISI ANFANI TOPO NIPA BI ASE NLO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN ATI FUN ONA ABAYO.

FUN EYIN FANS MI TIE BAFE FUNMI NI EBUN ๐Ÿ‘‡๐Ÿ‘‡
ACCOUNT NUMBER MI RE:-
9029903746
OPAY

ISE ATUDE ATI ASINA TADAJU ....ISE YII KONA WA LOWO JU  #150 LO..E LO DARAPO MON GROUP MI LORI FACEBOOK ORUKO GROUP YEN ...
16/07/2024

ISE ATUDE ATI ASINA TADAJU ....
ISE YII KONA WA LOWO JU #150 LO..
E LO DARAPO MON GROUP MI LORI FACEBOOK ORUKO GROUP YEN NI (ASIRI ATUDE PELU OSHOOLE TODAJU) TORI TOBA YA INU GROUP MI NIKAN NI MA MA POST SI..HMMMMM gbogbo e yin oloriburuku WOLI, ALFA, BABALAWO 419, ONIJIBITI ti e tu dakun isoro awon eniyan olohun ma binu si yii gbogbo eleda awon ABIYAMON ma bayii ja...
IKILO.. enikeni toba so fun mi wipe alfa ni mi wipe koye kin ma post si Facebook walahi koni da fun iru enibe Tori wipe ojojumo ni awon onijibiti ba ise WOLI, ALFA ATI BABALAWO je oloriburuku yii eo ri nkan se si walahi eni to ba pe(call) or message me wipe kin ma post si Facebook walahi ma fun iru enibe ni epe ni Tori wipe ise ti olohun ran mi ni mon je....kabiesi olodumare...opolopo okunrin ati obinrin lo ti wo inu ide nipa ibalopo ..opolopo eniyan ni awon Agba ti de monle nitori ogo ti onitoun ni hmmmmm eniti o ba wa ninu ide nkan oni lo dede fun Toba dara fun laro yio tu daru die lowo osan ti koba mura si adura daada haaa ojo ale re ni yio buru ju...E je kin mu enu duro na ... ATUDE ....AO LO WA EYIN IBILE TOBA MON DADAA KAN (ONE LOCAL EGG) TOBA WA TI DI ALE TI E TI FE SUN (SLEEP) AO WA BO SI ITA GBANGBAN AO WA BO ARA WA SI IHOHO OMOLUABI...moti so funyin wipe Woli temi yato si gbogbo awon woli to wa Lori Facebook ise ti olohun ran mi ni Mon je.. opolopo awon eniyan lo ti je anfani mi lati online... Iwo na ma dake ki Tarare ma bao dake pe mi fun ona abayo 09029903746..AO WA MA FI EYIN IBILE YEN NU GBOGBO ARA WA LATI ORI T**I DE ESE(LEG) BI A SE FI EYIN YEN NU ARA NI AO MA SE ADURA ITUSILE SI HMMM E bami share post yii kakiri group ki opolopo awon eniyan le je anfani re eniti ko ba ti comment tabi ko share post yii walahi ise yii koni je fun.. BI A BA TI SE ADURA SI BI ISEJU MARUN EO WA LO FO EYIN YEN MON ORITA META TABI KA LO JU SI ORI AKITAN TOBA TOBI DAADAA.. hmmmm Iwo na ma wo arare ni ran ...tete pe number mi fun ona abayo ati adura 09029903746

IWOSAN FUN ARUN ROPAROSE(STROKE)KOSI BI AISAN NA SELE NI AGBARA TO.. TIKO NI IWOSAN NIPA LILO EWE ATI EGBO.. BE SINI KOS...
16/07/2024

IWOSAN FUN ARUN ROPAROSE(STROKE)

KOSI BI AISAN NA SELE NI AGBARA TO.. TIKO NI IWOSAN NIPA LILO EWE ATI EGBO.. BE SINI KOSI BI OGUN SELE POTO TIKO NI ONA ABAYO NIPA LILO EWE ATI EGBO.. AFI TI AO BATI BA OTITO PADE LOYA KU..

GBOGBO ILE PATAPATA AO NI FI AISAN LOGBA OO..

ISENA RE:-
Ao wa orogbo meji, kanfura pelebe meji, ao lo kuna daada, ao da omi gbigbona si ao mamu ni sibi kookan laro ati ale, Ti oba tan ao tun semi t**i ti yio fi ri iwosan, pelu ase olorun yio ri iwosan.. Tio bafe ki asiri yi sise fun oo daadaa koko share re si opolopo group, kio si fi comment re se adura fun mi kio to dawo le...

SE AMIN ADURA YII.. AISAN TIKO GBOGUN KONI SEWA TOMOTOMO..

DONT_DIE_IN_SILENCE.

GBOGBO IGBA NAKO NI OWO, OWO, SE ITOJU ARARE ALAFIA SE KOKO.
AISAN BURUKU KONI KOLU WA.. OGUN TI YIO JU OJO ORI WALO OLOHUN KONI FI KAN WA.. E SE AMIN ADURA..

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO

ENITI ISE YII BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MON BIO SEFESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09029903746) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE

FUN IBEERE TIONI ITUMON ATI FUN IRANLOWO ONAABAYO SI GBOGBO ISORO AYERE CALL OR WHATSAPP TIOBA NIGBAGBO (( 09029903746)

AGBO OKUNRIN TIKO LESE DAADA
AGBO IDAKOLE
AGBO JEDI
AGBO INFECTION
NKAN OSU TO NSE SEGESEGE
AGBO IBA
AGBO ITO SUGAR
AGBO HEPAT**IS
AGBO GONORRHEA
AGBO FUN ENITI WA OYUN
AGBO STROKE
AGBO HIV/AID
ATI BEEBE LOO...

Message me on WhatsApp or call me
09029903746

Salam Aleikum Moki gbogbo Ajunilo inu ile yi oooo ki Olohun tun bo ma Tara wa Shea ise iyanu Ise yi ina ni omo irara!!!I...
11/07/2024

Salam Aleikum
Moki gbogbo Ajunilo inu ile yi oooo ki Olohun tun bo ma Tara wa Shea ise iyanu

Ise yi ina ni omo irara!!!
Ipe ni Ton shise bi Afose lati pe lakaye iyawo wa tabi onigbese wa ti o fe San owo fun wa

Ise nare
Ipe ni ton shise bi Afose

ERONJA
AKEKE METTA (3)
ORI OKA TONI ASE LENU KAN
ATARE

SISERE
AO JO PAPO TIO BA JO TAN AO YA HAAA SI NI EMETA AO PE ORUKO ENI NA PELU IYARE AO SO OHUN TA BA FE KIO SE EKANA NI AO LO ENI YEN NI KA FI BA SORO WALAIII ISE NLA NI MEJI METTA NONI ASIRI JU OGUN LO

DUPE LOWO ONI SABABI RE
FUN IRAWO TABI IRU ISE LATI SE LOWO WA
WHATSAPP / CALL :09029903746

AKU OJUMO ENI ADURA WA A GBA.ELEYI NI ASIRI CASH OUT BEAD.Fun anfani awon ti won n beere funElobami wa awon eronja yiEwe...
12/06/2024

AKU OJUMO ENI ADURA WA A GBA.

ELEYI NI ASIRI CASH OUT BEAD.

Fun anfani awon ti won n beere fun

Elobami wa awon eronja yi
Ewe Ogbo
Igo Funfun
Ileke Funfun
Odidi Atare 1
Ewe Amunimuye
Ito Idaji Eni Tofe Sise naa

Sisere==>Aomu odidi atare yan aoyin gbogbo omo inu re sinu igo funfun yan ti inkankan o gbodo yo sonu ninu re,aowa lo ewe amunimuye pelu ewe ogbo yan papo,aoko le ori atare naa ninu igo funfun yan,aowa fi ileke yan le lori,leyin naa aoda ito idaji eni naa si,aowa gbe pamo sibikan fun ojo meje,leyin ojo keje aolo gbe,aowa lo fรณ igo naa si ori akitan,aomu ileke naa aomaa fi si owo.
Note==>Aoni lo omo atare yan o.

Fun ibeere ๐Ÿ‘‰ 09029903746

Lati owo alase ati oludasile==>Tewe Tegbo Ti Olorun Ni
Like,comment kio share re losi group miran fun anfani elomiran.

Address

Ibadan

Telephone

+2348043339487

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri aye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share