Ogun ibile todaju

Ogun ibile todaju ogboju le ogun somo aje niko alias ewe gbogbo kiki oogun

07/08/2020

confirm,dan woo lobi iya okere ,ODAJU

29/07/2020

ekale,gbogbo ile,ese ti e n fi okan bami lo,paapaa julo awon ti won sese n darapo mowa,mosi tun n fi asiko yii dupe lowo eyin ti ewa sise lodo mi lose tokoja
ilera logun oro,ewe ama je fun gbogbo wa ooooo.

28/07/2020

IFERAN ATINUDENU
ao wa owo eyo ti ko luju kan,ao fi sinu okele eba,ao wa gbe mi,ao yo kuro ninu igbe wa ni ojo keji,ao sa gbe daadaa,ao wa lo kuna,ao wa fi sinu ounje fun eni naa je oti di oko tabi iyawo yin niyen.
obinrin naa le lo fun okunrin
EMI NI TIYIN NTOOTO
OKO OLOYUN 1
ESE PUPO.

28/07/2020

AJEGUN TODAJU
ewe dagunro ao jo papo mo atare ajah kan,ao sin gbere si orun owo wa mejeji yipo,ao si tun la die nbe.
odaju

20/06/2020

ASIRI TI A FI MO ENI TO N SE WA
odidi opolo ijokun nla kan,epo pupa ilaji igo,epo obo,epo igi nla, odidi atare nla kan, ose ebe,kankan ibile meta.
SISE RE:ao gun epo obo ati epo igi nla pelu atare papo,ao la enu opolo yen,ao wa kii eroja yisi nikun t**i ti yio fi yo bamu,ao se adura si leti otun, epe si leti osi bi a se fe kii aye onitohun ri,ao wa gbe ikoko kana,ao da epo pupa si ,ao wa kona mo t**i ti yio fi gba daadaa,ao wa ju opolo aiye na si, ao wa depa t**i ti epo yen yio fi gbe mo lara ao so kale,ao pomo ose dudu yen pelu olokun die
HMMMM, O TI DI OOGUN ABENU GOOGOO
lilo re:ao bu die si are kankan ibile na,ao ma fi we pelu epe,bi a se fi ki eni na se sesin.obinrin na lelo.
EWO RE:a ko gbodo sunkun bi o ti wun ki eni na sunmowa to
EMI NAA NI
AWODOKUN
IFASAKIN
OKO OLOYUN 1
IRE OOO.

20/06/2020

OGUN OYUN SISE,/ ABOTTION OF PREGNANCY TODAJU
eso iyalode funfun, ewe gbegbe oojo,a o lo mejeji papo ti yio kuna daadaa,ao wa se leponiyo pelu igbin apinu kan,ao fi ata ijosi si,odi jije
EMI NA NI,AWODOKUN- IFASAKIN OKO OLOYUN 1
IRE OOO.

18/06/2020

OBA OSE AWURE OLA TODAJU
odidi oga kan,iye agbe kan,aluko kan ididere kan,inkan osu iyamopo die, ao jo papo,ao lo kuna daadaa lori olo,ao wa te etu ogun.
IFA ESEKAN OLA:ao wa pe ohun re si,ao wa pomo ose dudu,ao wa ko sinu fitila oloju kan.
HMMMM,DANWO LOBI IYA OKERE,100/ SURE
ESE IFA NAA RE
o o
o o o
o o o
o o
NKO PARI ISE YI,AMO TI O BA WUN YIN LATI DI OLOLA LARIN AWUJO,E KAN SIMI LORI AGO,MOFI OLORUN BURA KONI IPALARA KANKAN RARA,MOTI SE FUN OPOLOPO ENIYAN TI WON SI N JERI ISE NA PELU FIFI EMI IMORE HAN SIMI.
SE TIE LONI KO BO LOWO ISE.
EMI NITIYIN NTOOTO ,AWODOKUN IFA SAKIN
OKO OLOYUN 1
IRE OOOO.

11/06/2020

OGUN HIV / AIDS TODAJU
ewe rinrin oojo,ewe akintola ,ewe imi esu ti a n pe ni renrinkomi, alubasa elewe,ao ju etale pupa , ao gun papo
LILO RE :eko gbigbona tabi omi gbigbona laaro laaro, idaji sibi meta meta leyin osu kan,e le se ayewo ara yin ire ni oo
EMI NI TIYIN N TOOTO
OKO OLOYUN 1
ALAFIA.

10/06/2020

AFOSE AGBOOJO TO SISE OLUGBOHUN
ewe ewuro,iyo isebe die,orogbo kan,oko atare kan,opolo ijokun oye kan,iwo agbonrin kan,ose dudu,ikoti ide kan
sise re: a o fi ito idaji aifohun gboewe adun oojo naa ao ro ito na sinu isasun kekere kan pelu opolo ijokun kan si,orogbo kan ........... ati bee bee lo.
LATI SE E KAN SIMI LORI AGO TABI KI E COMENT SABE ISORI YII
EMI NI TIYIN NTOOTO,
OKO OLOYUN 1
ESE PUPO.

26/05/2020

e ku ale oo gbogbo ile,ogun itaja todaju fun gbogbo eniyan ti wa ni arowoto yin bayi,fun iwo to o ko ri oja ta,o polongo, polongo amo bakan na lo n kuse ,e ma lagun jima e kan si emi oko oloyun 1 ni ijebu igbo,asiri wa yio ma bo oo,ao si ni wa bakan na mo,esami adura.
fun iwo ti o ba nilo re,e koment si abe isori yii,ese pupo.

Address

Ibadan

Telephone

+2348168614316

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ogun ibile todaju posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share