Yara Asiri Imo Awon Woli

Yara Asiri Imo Awon Woli Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Yara Asiri Imo Awon Woli, Consulting Agency, Ibadan.

OSHOLE OWO NLA, MA BOSI KU. TI ORE GIDI NFI WOLE* Ado ide to ba tobi die * Ako alangba ti ori re pon daadaa kan* Igba ol...
13/08/2026

OSHOLE OWO NLA, MA BOSI KU. TI ORE GIDI NFI WOLE

* Ado ide to ba tobi die
* Ako alangba ti ori re pon daadaa kan
* Igba olomori kan
* Abo alangba to ti gbo daadaa kan
* Odindi Atare meji
* A o lo kan ipoti (box) ti a fi igi IROKO se lodo awon carpenter
* Ose dudu
- A o jo ako alangba pelu odindi Atare kan
- A o lo kunna daadaa
- A o po mo ose dudu
- A o ko ose na sinu Igba olomori kan
- A o gbe Igba na sinu apoti (box) onigi iroko yen
- A o de pa
- A o tun jo abo alangba pelu odindi Atare kan
- A o lo kunna daadaa
- A o ro ebu na sinu ado ide
- A o wa gbe ado ide na bo aarin ose ti o ti wa ninu apoti tele
- A o de apoti na pa fun ojo meta.
LILO RE: A o koko shi apoti yen, a o shi omori-igba, a o tun shi ideri ado ide yen
A o sese wa bu ose na
A o se adura owo nlanla si ose na
A o fi si ara kainkain ibile tuntun kan
A o sese wa de won pada gege bi a se ye ko se wa.
A o lo fi ose na we.

SAARA RE TI A O MA SE
A o ma run ekuru funfun sinu apoti na ni eekan lose.

AKIYESI: Ti ekuru funfun yen ba tin po sinu apoti na, a o ma fi owo (hand) ko kuro ninu apoti na, a o lo ma da nu sori akitan.

Ojo Monday ati ojo Thursday nikan ni a o ma fi ose na we laarin ose.

Kainkain kan soso ti a ba ti koko lo na ni a o ma lo t**i ose na yio fi tan (Jowo je ki kainkain na tobi daada)

Ti a ba ri enikeni ti o koko gbiyanju ise yi ninu group yi, ki o ba wa so bi agbara ise yi se ri. A ma ju wa se ooo.

COMMENT KO SHARE RE KOLE JE FUN O

🤟Every day is for checking (AYEWO) 9am to 9pm send your name for checking ayewo nipa igbesi aye re

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO

CALL OR WHATSAPP
08141522303
09025458130

👊IMO AWON WOLI
👊KONI TOWO MI BAJE

👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE.

OSOLE  ALAJOLA  AJOLOWO OPO ENIYAN LE LOape tuntun kan sori ina, epa iya ewure dudu minrin - minrin kan tio ti bimon dad...
31/07/2026

OSOLE ALAJOLA AJOLOWO OPO ENIYAN LE LO

ape tuntun kan sori ina, epa iya ewure dudu minrin - minrin kan tio ti bimon dada, kie gba gbogbo eje re sinu ape yii, ege ori re pelu ese re mererin sinu ape yii, odidi igun tifun tifun ori akala to reru daada, ori agbigbo, eye kowee dudu, ikode meje pelu odidi atare mefa, eko gbogbo repo sinu ape tio bajo tan, kia loo kunna.

LILORE: Ao ra igo epo pupa kan, igo oyin ao po mejeeji po daada, sinu ike funfun olomori tio fe die ao yo ekun sibi meji oogun yi sii, ao tun roopo daada, ao maa loo ni sibi meji- meji ni aroorun, laro kutu.

IKILO: Enikeni tio bati je ninu eran yi ko gbogbo lo oogun yio, bi olohun ba younda fun o lati se ise yii, ni gbogbo igba ti oba wa laayo, waa maa sadura funmi saa ni iyen naa tito mi, nitorpe iwo naa ti gun aga*o tio ga ninu awon aga*o ola niyen.

OFORE: Koweeeeee (3) owo mi eluju odan, owo mi eluju niki olo bami gbewa, ota mi eluju niki olo bami pa

, bi igunugun ba nlo lori ile oju re a tole atode gbogbo ohun toba nbo wa niki emaa fi imole re hanmi, bi akalamagbo ba nlo lode orun, owo nla-nla ni ya wole, owo nla-nla nki eya simi, ema ya iku somo mi, ema ya arun somo mi, ema ya iku si yawo mi, ema ya arun si iyawo mi, sebi latorun lagbigbo ti reru aje re waye, agbigbo parada (3) walo re ru owo nla-nla wa fun emi lagbaja omo lagbaja, ileku kekere lewure ndun, ki ile emi lagbaja omo lagbaja kun kekere fun owo nla-nla, adua ejiogbe nifa re,

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

OSE EYONU AYE TODAJUOmo olongbo kekere aye kan, epo obo die, ewe orijin ojo die  ewe akoko ojo die, ewe ajeobale ojo die...
24/07/2026

OSE EYONU AYE TODAJU

Omo olongbo kekere aye kan, epo obo die, ewe orijin ojo die ewe akoko ojo die, ewe ajeobale ojo die, ose ibile pupo die, awo funfun olomori kan,, apo asunhan a*o funfun kan odo ti won nfi gunyan,

SISE RE
Ao la omo olongbo na mole ti yio ku, ao bo gbogbo awo ara re,patapata ao iyoku sinu odo ti won nfi gun iyan je, ao gun pelu awon eroja yoku, pelu ose ao wa fi awo olongbo ti a bo yi tele awo funfun na ao ko ose yi le lori ao wa fi awo to seku sita bo lori dada ao wa fi ideri awo yi de pa, ao wa gbe sinu apo asunhan a*o funfun ti a ran yi ao gbe ko si ibikan fun ojo meje,ao wa ma fiwe ni emeji lose, ojo Tuesday ati Friday
Ose eyonu aye to confirm ni oooooooo

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

02/07/2026

ASEJE OLA TI ENIYAN FINDI ENIYAN NLA ATI OLOKIKI

Omunu ewe akoko to o kangun soke, ati eyiti o kangun si isale, isasun tuntun ( obe ide, ati sibi ide ) ao lo omunu ewe yì papo pelu iyere ao ra odidi elede ao pa ao yo ekiri 16 Eran elede to tobi, ao pin iyoku fun awon eyan oti schnapp ati ila ji oyin igo kan ni a fıse je, ao friyo si, a kogbodo fı epo si, nigbati obe yi bade ori ina tan ada ide ati sibi ide ni ama fıro obe yi t**i yio fı jinna, ao jeki otutu dada ao fıiyere osun te ifa e jiobe merindinlogun si oju opon ifa, ao pe ofo re si ao wa da sinu obe na, ni owuro ojo keji ni ao je, ki ato soro si eniyan, ao te eni tuntun, ao te a*o funfun le lori, ao wo a*o funfun sokoto funfun, gbogbo ohun ti abawo gbodo je funfun, ao wa se gege bi OBA, ao wa je obe na lai soro si eniyan ti ao fi jetan, inu ile wa ni ama wa t**i ile ojo na yio fısu ako gbodo dobale fun enikeni ni ojo ti abalo ise yì, ao si gbodo fıoju kan (olojo) (orun sun) ni ojo na
GOLOHUN RE_: Ifa jeki ori san emi -omo- ori losan jinwin jinwin ti
ofi di olola, ifa jeki ori san emi -omo-..
Ori losan kutukutu oba orisa ti ofidi oloro, olodumare o di oju kan, o la okan, o ka ese ro, o gbe asan egede re lowo oni ohun yio pa gbogbo won lotu if e tomotomo, wonni nitori kinni?
O ni nitori kekere ife ni won njo ma nsin oni, agbalagba ife won njo ma sin oni, un o sin, un o sin ni olongbo nke,
odifa fun alara, alara la yebeyebe ogbe Ade baba re o fı de ori, adifa fun ajero, ajero la yebeyebe o gbe ade baba re o fıde ori, odifa fun Ajero, Ajero la yebeyebe o gbe ade baba re o fı de ori, odifa fun owa orangun aga orangun ile ila ohun na la yebeyebe, o gbe Ade baba re ofi de ori, odifa fun Oba Benin omo ori okuntayo omo afi ide se opo ile, ohun na la yebeyebe ogbe Ade baba re o fıde ori, odifa fun olofm erin-min- jinwin jinwin, ohun na la yebeyebe o gbe Ade baba re o fi de ori, odifa fun oba i jebu ode ögboro-Godonida omo arogun ohun na la yebeyebe, ogbe Ade baba re ofi de ori.
Wonni oti wa je (eyiatiri) ti gbogbo won fi de Ade ori rereere, mo ni eyin komo pe epo kepo ki dun kobori oyin, Alade mo fi elede rubo, gbede kara o demi o gbedegbed, mo ni eyin komo wipe, obe kobe ki pon ko bori ide, Alade mofi elede rubo, gbede kara o demi gbedegbede, mo mo eyın komo pe? Akı? ti ewe kewe joye leyın akoko, Alade mo ti elede rubo kı ara o demi gbedegbede, Monı eyın o mo pe ita kita ki bori e jiogbe merindinlogun Alade mofı elede rubo kara o de mi gedegbede, Monı eyın o mo pe otı kotı kan kı borı otı oyınbo Alade mo fi elede rubo kara o demi o abedegbede, Moni atosan atoru lamo ala*o funfun, Alade moti fi elede rubo, Kara o demi gbedegbede,
N B. leyin to aba je obe yi tan ao wa so obe ide ati sibi ide ti a fi ro obe na ako sinu apo a*o funfun, ao ma pa oruko ati ekuru funfun bo o lododun
OSO OWO NLA NI KISI BATI

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

29/06/2026

ASEJE EBE AWON AGBALAGBA

ewe ajeobale, ewe Aje, ewe aluki, Ileke sesefun ileke ifa igbin to pinnu meji iyere die, ao no igbin meji, ao fo dada ao fi penpen ge si, ona mejo mejo, ao se lepo ni yo, ti o ba tutu tan ao fi iyere osun te ifa osa meji, ao pe ofo si, ao da sinu obe na, ao je

Gbolohun re
AGBADA NLA LORUKO TI A NPE AYE,3x ARABA NTASI LORUKO TI AN PE IWO ESU ODARA LALE IFE,3x bi aba fi efun fun aye nse ni ara aye nya gaga, bi aba se ipese fun ogun nse ni ara ogun nle koko, omo won ni ile Ife lobi atepe, bi o ba ri be ajepe emi. - omo. - ma ba won te ile yi pe, omode loni ki ma bawon te ile yipe agba loni ki nma bawon te ile yi pe, aku bi aja se nku tohun ti olugboro omode atagba loni ki nma bawon te ile yi pe aku bi agutan ti ku ti ohun ti bolobolo enu re, eye se eye, eye fi apa se, eye se eye eye fi ese se, eye dele alara o pa omo alara, eye dele ajero o pa omo ajero, eye dele orangun ile ila o pa omo orangun ile ila, eye gbera o wo ile aja ngbo wee wewe, awo ile alara eye pawon, eye gbera o di ile bonbon lagutan nwo, awo ajero eye pawon, eye gbera o di ile afike areke ohun gangan na nke awo orangun ile ila eye pawon, wonni ibo ni I awon awo k**i, eye gbera odi ile Orunmila, wonni baba aboru aboye, wonni orunmila awon yio pa o, awon yio pa awon omo re, awon yio pa awon alaboyun ile re, Orunmila ni eyin kole pa mi, eko le pami lomo eko le pa alaboyun ile mi, eko le ba ise owo mi je, Orunmila ni se bi amusoro ni oruko ti eyin iya Aje nje, atedo je okan ni oruko ti eyin baba Aje nje, owara kanrakanra ni oruko ti eyin Aje nje, Awon iya ni o di oro ewo, wonni Orunmila lati o ni yi lo, ki o lo wa igbin meji ki o lowa ewe aluki, ki o
Lo wa ewe ajeobale, ki o lowa ewe sefunsefun ki o lo wa ileke oturupon, ki o lowa ileke seseefun, wonni gbogbo eniti o ba ti je ninu aseje yi, aluki ti nbe fun, awon yio ma bowo fun oluwa re, awon yio si ma yonu si oluwa re, won yio kesi osa meji wipe ohun lo difa to mu awon eleye wasi ile aye, OSA MEJI OOO 3x gbogbo ire mi ti nbe lori gun merein Agbala aye, Kewa sajo fun emi-omo- nitori bi omo bafa irun ori re a di omo tuntun, ti agba ba fa irun ori re adi omo tuntun mo di omo tuntun lodo omode loni, mo di agbalagba lodo omo tuntun loni, mo di omo tuntun lodo okunrin le ni, mo di omo tuntun lodo obinrin leni, gbogbo ire tuntun lojo to tipe, ati nisinsinyi, ki e lo sajo wa fun emi - omo - ki e ko simi lowo, ire owo ire omo ire moto ire Alanu etc ki o to mi lowo lati oni lo,

N b ao gbe ipese eko tutu kan ni ale ojo aba je aseje yi

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

01/06/2026

EYONU OSOLE TAKO TABO TODAJU
ako alangba 16,abo alangba 16,egbo
tude tiwon disi ona 16, opolopo eso
yerepe, opolopo ewe ewuro
oojo,odidi atare 16,akuko adie
totobi kan,abo adie toti bimori
kan,ao ko alangba fi tele ape
tuntun,ao ko egbo tude si, opolopo
eso yerepe ao ko si,opolopo ewe
ewuro taja lojoo ao kosi,atare ao
kosi,ao jopo,toba jotan,ao lo ti yio
kunu dada,ao pin si ona meji,ao po
idakan mose dudu ,eje abo adie yen
lama pa fun ose yen ,ao ko sinu ike
funfun,ao wa sere kan ao ro idakeji
ogun yen si,ao pa eje akuko adie
yen si,ao le iye re mo sere yen
lara,ao gbe mejeji si aye owo,ao
mafi ose yen we lararo kutukutu,ao
si mafi ebu yen fo eko tutu mu leyin
re,eniti eledua bafun ni iyanda ise
yi se,kosora pupo tori pe omanko
obinrin wa pupo ju taba tinlo ise
yi,ti ara bati hunwa,ao gba alejo
toni owo lowo niye ,ako gbodo
ara,teyan ba hoo ara alejo yen
mawa sugbon koni mu owo wa,ise
yi daju,(akiyesi)awon adie mejeji
yen,ao fi se Sara fun awon
eyan,sugbon eni toni ise kogbodo je
nibe o,


SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

28/05/2026

OSOLE OWO TODAJU LARIN OSE
KAN SI MEJI
(1),iye agbe meje (7),iye aluko meje
(7),ori agbe kan (1),ori aluko kan
(1),ori odidere kan (1),ewe aje tutu
tabi gbigbe,ewe biran tutu tabi
gbigbe,ewe anu tutu tabi gbigbe,ao
gunpo,ao wapo mose dudu,ao wa
ori aguntan tiwonpa loojo, gbogbo
owo paper tanna pata,ao ko awon
owo yen sinu awo funfun olomori
kan,ao gbe ori aguntan si,ao ko ose
yen si,ao wagbe ose yen sinu apo
asunwon funfun,ao gbe ko soke,idi
re kogbodo kanle mo o,ao ma buwe
laro laro,

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

OSHO GBEMIPADE OLOOREORI ODIDERE KAN,ORI ALUKO KAN,ORI AGBE KAN,EWE ALUPAIDA 201 AO LO WONLOTOOTO,AO SESE WA DA WON PAPO...
16/05/2026

OSHO GBEMIPADE OLOORE

ORI ODIDERE KAN,ORI ALUKO KAN,ORI AGBE KAN,EWE ALUPAIDA 201 AO LO WON
LOTOOTO,AO SESE WA DA WON PAPO AO WA BU DIE TI ALE FI PO OSE IWE EEKAN
SOSO,AO FI SI ORI KAINKAIN TUNTUN KAN,AO WA LO ATA IJOSI LOTO AO DA PO MO
EBU IKEJI TO KU YEN AO FI SE AHON MALU TI A GESI MEFA JE PELU OMI OKUN,EPO
PUPA,TI O BA FE JINA TO KU DIE TI AO SO KALE AO FO EYIN ORORO META SII LORI
INA TI YIO JINA PAPO KI A TO SO OBE YEN KALE,AO TI LO FI IYEROSUN TEFA EJIOGBE
KALE LORI OPAN IFA TABI SORI AWO FUNFUN, IWAJU ODU YI LAMA SO ASEJE YII SI
AO WA DANIYAN SI DAADA(ADURA GBOWO WA GIDI NI AO SE SI OBE YIO) AO PA IFA EJIOGBE YEN
RE,AO WA TE IFA ODI MEJI AO FI SILE AO WA LO WE OSE YEN,AKO NI NU ARA O,A*O
FUNFUN NI AO RO SIDI LOSI ILE IWE,OUN NAA LA MAA RO FIJE ASEJE YEN TI A BATI
WE DE,AO DA IYEROSUN YEN SINU ASEJE YEN AO WA MAA RO PAPO PELU
GBOLOHUN YII:-IFA OWO NLANLA NI MO NRO PAPO YIO,OWO ILE RIRA,OWO ILE
KIKO,OWO MOTOR RIRA E.T.C KI TOKUNRIN,
TOBIRIN,TOMODE,TAGBA,TOLOWO,TOLORO KI WON MAA FI OWO NLANLA SAANU EMI
LAGBAJA OMO LAGBAJA ADURA.....AO MAA ROPO...ODI JIJE.
N:B-OJO ALAMISI NI SISE ASEJE YIO,TI A BA JE TAN AO WA MU A*O FUNFUN TI A RO
YEN AO KA SINU ISASUN YI, AO GBE OMORI ISASUN YEN SORI ISASUN AO DE PA AO GBE A*O FUNFUN YEN
SINU ISASUN YEN KI ATO DEE AO WA WE LOWU FUNFUN DIE KI IDERI RE MA BA SI
KURO,AO WA LO RIN MOLE NI ODI ILU KEJI WA(AKO GBODO RIN MOLE NINU ILU TI
ATI JE ASEJE YEN O,OLEWU O).SAARA RE AO FI AKARA ELEPO TABI MOSA SE SAARA
LOJO KEJI TI NSE OJO JIMOH. HMMMMM ODAJU PUPO

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

OSOLE ILE KIKO TABI MOTO RIRATODAJUodidi eye kannakanna aye kan,iyeeye okin merin,iye eye osinmerin,iye akala merin, opo...
16/05/2026

OSOLE ILE KIKO TABI MOTO RIRA
TODAJU
odidi eye kannakanna aye kan,iye
eye okin merin,iye eye osin
merin,iye akala merin, opolopo
ileke itun ati ifa,obi ifin oloju merin
kan,owo #1000 tuntun,ao lo awon
eroja yipo,ao fise eye kannakanna
yi ni aseje pelu iyere lepo niyo,ao fi
iyerun osun tefa ejiogbe,ao pe ohun
re si,ao da si obe na,ao je,ao ma
wipe,okin alade loni kiwon demi
lade moto tabi ile,osin loni ki omo
araye mafi ohun gbogbo sinmi,itun
loni kiwon wa funmi ni moto
tohunmi loni,ifa loni ki awon
eniyan ra moto temi wa funmi
loni,igbe owonyabo owonyabo ni
kannakanna nke,ki omo araye gbe
moto temi wa funmi loni,kiwon
mafi tami lore loni,toba je moto
lafe,ao so kokoro moto sinu obe
na,toba je ile lafe ko,ao so kokoro
ile sinu obe na,ti abanje obe yen
lowo ti anponla ao mapon kokoro
na la,eyin eyan mi tonwoju eledua
fun moto tabi ile kiko,elo bami dan
aseje yi wo,odaju

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

10/05/2026

IPESE FUN OHUNKOHUN
Eran maalu ekiri kan ao so fun awon eleran kiwon bawa ge rubutu ko tobi die ao wa fi
iyereosun tefa osameji soju opon ifa aofi ekiri eran yi siwaju odu yen aofi obi alawe
merin kan si eti opon ifa naa ao wa pe ohunre sinu odu yen Lenin naa aofi eran ko ifa
naa aofi sinu awo ipese tuntun kan ao bu epo lelori aofi obi yen bere ibiti won yio ti gba
ipese na ni adugbo wa Toba di aro ojo keji aolo mu awo ipese yi wale lati tun fi se ipese
yi nigba miran OFORE:Ake kaaka wolu3× Abirin kakaka wolu3× A gbe ori iroko ke
kakaka3× Ibiti edarisi ni edari si3× ibiti e pin jeki si lepin jeki3× Eyin ni igba Erin ri tiwon
nfi eyin lu eyin omo opere opere3× Eyin ni igba efon ri tiwon nfiiwo lu Iwo omo
ogbangandanran ogbangandanran3×Eyin naa ni igba olopere ri tiwon fi nfo janpe janpe
kalu3×Ewa ni kinni igba Erin ri tiwon fi nfi eyin lu eyin omo opere opere Eni kinni igba
efon ri tiwon fi nfiwo luwo omo ogbangandanran ogbangandanran Ewa ni kinni igba
olopere ri tiwon fi nfo janpe janpe kalu Ero!ero!! Ero!!! Seese lodifa fun koowe ajedo
eniyan mabi Aje oronro masinto Eewo ni aje ko gbodo pa omo koowe je ki aje mapa
emi lol ooo Kiwon lo Lana rere gbogbo owo nlanla fun mi lati oni lo nio Nitoripe
agbadikaka3× loruko tanpe ifa orunmila ninu gbogbo eye to nfo radiradi loju orun eyin
iyami osoronga ati okanlerugba irunmole loba olodumare pinhun lode orun Won ni ki
olodumare fowo mu ode orun ko yonda ile aye fun awon ni kiakia olodumare fowo mu
ode orun osi yonda ile aye fun yin Nigbati e dele aye tan eyin iyami osoronga tunwa ba
orunmila pinhun wipe ki orunmila fowo mu aaro ati osan Awon ni awon ni oru won niti
orunmila bati pese fun awon loru awon yoo mase gbogbo nkan toba fe fun laro ati
losan orunmila wa biwon lere wipe kinni ohun ipese naa won niki orunmila mafi eran
abeje malu ekiri kan pelu iyereosun pese fun awon toba ti pe oruko awon awon yo
mase gbogbo ohun tobafe fun Ipese ti eniki orunmila se lojo kinni anaa ni emi L omo L
se fun yin loni yio Ti o base wipe lododo ati lotito leba nbe lode isalu aye yi ki ewa lo
pese gbogbo ohun ti mo bere funmi ni kiakia bayi oo adura ohun ti abafe kiwon se fun
wa ao gbe losi ibiti won tife gba....

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
CALL OR WHATSAPP

08141522303
👍 SHARE
👍 COMMENT
👍 LIKE
👍 FOLLOW DIS PAGE

Address

Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yara Asiri Imo Awon Woli posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share