Eje Ka Jo Gbe Isese Laruge - Erinfolami

Eje Ka Jo Gbe Isese Laruge - Erinfolami A gbe egbe yii kale lati maa fi tewetegbo se omo araye loore. Ki Olorun ranwa lowo. Ase Edumare

16/02/2025

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Yekeen Saheed Legacy Ventures, Amanda Cunninghams

04/10/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Chieu Nguyen, Vido King

29/08/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Abiodun Oluwayomi, Bolaji Olanipekun

OTURA ORILANA 2024 .Good morning my people,  trust you had an awesome night,  I pray this morning that our head will lea...
06/06/2024

OTURA ORILANA 2024 .
Good morning my people, trust you had an awesome night, I pray this morning that our head will lead us to the right path in life aṣẹ.
Let us use this holy corpus of Otura orire/orilana/Ekundayọ/eleji/afoji as it revealed from world Ifá festival at òkè itaṣẹ Ile-ifẹ 2024.

Ifa advised each and everyone to venerate his/her Ori with two kola nuts, white rooster and water.
Ifá said it is our ori(head) that will lead us to the land of our promises, and for our head not to allow negative forces to enter us.
Hear what the corpus said;

Ọrúnmìlà said ọgbẹrẹgẹdẹ
I said it is otura orilana sacrifices that comes
Ọ̀rúnmìlà said what shall we use to offer otura orilana sacrifices?
I replied two dry mouse
Ọ̀rúnmìlà said no!

Ọrúnmìlà said ọgbẹrẹgẹdẹ
I said it is otura orilana sacrifices that comes
Ọ̀rúnmìlà said what shall we use to offer otura orilana sacrifices?
I replied two dry big fishes
Ọ̀rúnmìlà said no!

Ọrúnmìlà said ọgbẹrẹgẹdẹ
I said it is otura orilana sacrifices that comes
Ọ̀rúnmìlà said what shall we use to offer otura orilana sacrifices?
I replied two hens with big liver
Ọ̀rúnmìlà said no!

Ọrúnmìlà said ọgbẹrẹgẹdẹ
I said it is otura orilana sacrifices that comes
Ọ̀rúnmìlà said what shall we use to offer otura orilana sacrifices?
I replied two goats with big breast
Ọ̀rúnmìlà said no!

I said, Ọ̀rúnmìlà I declared my innocent please cover me up, mapo ẹlẹjẹlu mọba ọtun a short deity of igẹti hill, what is the sacrifices of otura orilana?
Ọ̀rúnmìlà said if i neither have wisdom nor knowledge didn't i know it is two big kola nuts, white rooster and water is the sacrifices of otura orilana
Ọ̀rúnmìlà said that is what his diviner will use to venerate his/her head so that everything can be greatly good for him/her.

My people, I pray this morning that our head will not return back from us, may our head accompany us to where our success and prosperity lies and it will never allow evil forces to befall us, we shall never experience sickness in life àṣẹ.

YORUBA VERSION
Ẹkaarọ ẹyin ènìyàn mi, aòjíire bí? Oni a sanwa o, moṣe ni ìwúre laarọ yi wípé ori wa yio lana ire gbogbo funwa o àṣẹ.
Ẹ jeki a fi odù ifá mímọ Otura orire/orilana/Ekundayọ/eleji/afoji to jáde níbi ọdún Ifá àgbáyé tí wọn ṣe ni òkè ọlọta ni Ile-ifẹ yi ṣe ìwúre ti aarọ yi.

Ifá yi gbawa níyànjú wípé kí a bọ ori wa pẹlu obi togbo meji, Àkùkọ adiyẹ funfun ati igba omi tutu, ifa ni ori wa yio sinwa débi ayọ wa, ori wa yio si ṣe alatilẹyin wa, bẹ́ẹ̀ sini koni gba abọde ibi kankan funwa.
Ifá náà ki bayi wipe;

Ọ̀rúnmìlà ni ọgbẹrẹgẹdẹ
Moni ẹbọ otura orilana de
Ọ̀rúnmìlà ni kini ẹbọ otura orilana?
Moni eku méjì Olúwéré
Ọ̀rúnmìlà ni ki ńṣe eku méjì Olúwéré

Ọ̀rúnmìlà ni ọgbẹrẹgẹdẹ
Moni ẹbọ otura orilana de
Ọ̀rúnmìlà ni kini ẹbọ otura orilana?
Moni ẹja méjì abiwẹgbada
Ọ̀rúnmìlà ni ki ńṣe ẹja méjì abiwẹgbada

Ọ̀rúnmìlà ni ọgbẹrẹgẹdẹ
Moni ẹbọ otura orilana de
Ọ̀rúnmìlà ni kini ẹbọ otura orilana?
Moni agbebọ adiyẹ méjì abẹdọlukẹlukẹ
Ọ̀rúnmìlà ni ki ńṣe agbebọ adiyẹ méjì abẹdọlukẹlukẹ

Ọ̀rúnmìlà ni ọgbẹrẹgẹdẹ
Moni ẹbọ otura orilana de
Ọ̀rúnmìlà ni kini ẹbọ otura orilana?
Moni ewurẹ méjì abamurẹdẹrẹdẹ
Ọ̀rúnmìlà ni ki ńṣe ewurẹ méjì abamurẹdẹrẹdẹ o

Moni Ọ̀rúnmìlà mojẹwọ ọbun ki o daṣọ romi, mapo ẹlẹjẹlu mọba ọtun ọmọ ọkinkin ti meyin erin fọn gbọlajoko ọmọ erin ti fọn fikan gbuu lọ́nà àlọ, ọkùnrin kúkúrú oke igẹti
Moni kini ẹbọ otura orilana?
Ọ̀rúnmìlà ni bi mi o tiẹ gbọn, bí mi o ti ẹ mọran oni ṣemi ko mọ wipe obi meji, Àkùkọ adiyẹ funfun ati igba omi tutu ni ẹbọ otura orilana ni

Ọ̀rúnmìlà ni ki wọn sọfun Akápò toun kí ó máa fi bọ ori rẹ, oni ori rẹ yio gbe débi tí ire ẹ wa, ori rẹ kosi ni gbabọde ajogun ibi.
Ẹyin ènìyàn mi, moṣe ni ìwúre laarọ yi wípé ori wa yio muwa delẹ ileri, ori wa koni gbabọde ibi, ori yio lana aje, ọmọ, ọkọ àti aya funwa o ààaṣẹ.
ÀBỌRÚ ÀBỌYÈ OOO.

HAPPY NEW  WESTERN YEAR TO ALL MY LOVERS ACROSS THE GLOBE.I pray this year 2024 will be a wonderful year for us, may we ...
03/01/2024

HAPPY NEW WESTERN YEAR TO ALL MY LOVERS ACROSS THE GLOBE.
I pray this year 2024 will be a wonderful year for us, may we seek the mercy of Eledumare àṣẹ.

It is Ogbe ọkanran that revealed for this year 2024, Ifa foresee goodnesses of life, ifa said this year will be far better than last year in terms of financial breakthrough, ifa advised to appease ifa with two kola nuts and she goat.

2. Ifá also advised to appease ajé, and for those that haven't have the ajé icons should endeavor to do it, ifa said there will be circulation of money this year if you appease ajé very well, ifa advised to offer ajé two kola nuts, guinea fowl, honey, ekuru funfun.....by doing this ifa assured us of total financial breakthrough, and whatever we lay our hands upon shall be prosper.

3. Ifá said he will make things easier for us in this year, his guide and protection shall be upon us all. Here ifá advised to do the ifa medicines with tortoise shells, oorẹ pins, snail shells and tail of snake and Ifá leaves, this will be use with water anytime for the mercy to show up.

4. Ifá warned us this year to be very careful with our properties, ifa advised us that we shouldn't depend on or trust anyone more than ourselves, ifa said we should not send any of our properties through anybody in order to avoid been running away with the properties.
And also, we should not harbour or keep any properties that is not belongs to us in order to avoid arrow of death

5. Ifá advised the people in high post to offer sacrifices because of sudden death from office, ifa said they have done some evil things underneath that will be causing untimely death for whoever that install to the post.
Ifa advised to offer a giant Ram for Èṣù láàlú but it is a big stick that will be used to kill the ram instead of knife, that is when the trouble will be solved.

6. Ifa foresee blessings of children to barrenness, ifa said those that are seeking for the fruit of womb should appease ifa with two kola nuts, hen, brown mice, dry cat fish and snail, by doing this, ifa assured you of new baby in your house.

7. Ifá advised to offer sacrifices with all the farm crops, ifa said he won't let us experience faming and shortage of humans within our community,
Here, we will offer two kola nuts, he-goat, yam, plent of corns, unripe plantains, beans, millet and so on...

8. Ifa advised us especially men to be very careful because of our wives, ifa said we shouldn't give them much chance to be travelling this year so that another powerful person will not hold her down, to the extent we won't have choice than to leave her there
Ifa advised to offer two kola and rooster for our head, the ẹkinkun leaf will be used to tie the rooster legs, after the appeasement of head, the ẹkinkun leaf will be used for ifa protection incision on head, this won't allow anybody to take over our wives or properties

9. Ifá foresee goodness of high post this year, ifa said we shall be great, ifa advised to appease Ifá very well, and those that have Ifá should make sure they put "olodusọ" inside their Ifá as a king, so that we shall be given a high and big post.

10. Ifa advised on agriculture, ifa said we need to venture into agriculture because it will really pays in this year, farmers will cash out unexpected, ifa advised to offer he-goat for eṣu laalu, ifa said having done that, ifa assured an abundant goodness for us.

20/12/2022

Ise ti mo Fe funyin yii, koni je ki won gba ile yin, sugbon tie ba fi gba ile onile, e maa ku laarin Ojo meje, e ronu kie to se o.

KI WON MA LE YANWA JE GBA ILE WA
Ori oka nla kan, opolo ijokun nla kan, ao ge ese opolo yii mereerin, ao ko si enu Ori oka yen, ao fi odidi atare aja kan senu oka yen pelu ese opolo yii mereerin, ao di ori oka naa ni owu dudu ati funfun, ao daniyan si awon toni anfaani ati de ori ile naa (bi omo ati iyawo, awon egbon ati awon aburo wa), ao wa so wipe eni ba fe yanwa je gba ile wa, ki ejo san eni naa pa, ao ri mo Ori ile naa.

NB: Eni ba fe gba ile naa, ejo yoo san eni yen pa ni, koni ero, sugbon ti a ba lo fun ile ti kii se tiwa, iku ni o.

20/12/2022

Idoti Inu tabi Arun ibalopo lo maa n fa ki nnkan OSU maa se segesege

AGBO NKAN OSU OBINRIN TO N SE SEGESEGE
Ao ge bara si wewe,ao yo gbogbo egusi inu re kuro,ao ko sinu oru kekere kan,ao bu omidun le lori,ao se jinna ao je ko tutu,ao ma yo mu lararo ka to jeun,ao tun ma mun lalale ti obinrin/okunrin na bati fesun.

NOTE: Agbo yi ma n ya yan ni igbe o,sugbon ko si ewu.

Ti igbe na ba ti n poju fun obinrin na,yio ma mu ni ekan lojumo niyen.

Omi lasan ni ẹni toni ulcer maa lo, koni lo omidun.

20/12/2022

Hi

17/11/2022

ASIRI TI WON FI MAN FI ISE OLOWO NLA WA ENIYAN KAKIRI TABI AWURE ISE

Eyin ororo tuntun meta, a o ko sinu ape a o da ewe ewuro oojo ati ewe orijin oojo bomo le, a o fi odidi atare kan si a o jo a o maa fi oyin lo.

17/11/2022

APE IFERAN
Igbalẹ tuntun
Epo pupa
Ọmọ atare meje

Ṣíṣe rẹ
Ao da epo pupa silẹ ninu yara wa ao wa gbe idi igbalẹ Yan le lori Ao ma fi ọmọ atare meje pe gbolohun rẹ láàrin oru

OFORE: Atuyaya amiyaya ẹyin lẹ damọ ni idagiri oganjọ 2X, mofẹ kẹ bami da Lagbaja ni idagiri oganjọ loni komale sun komale wo to ban sun èmi Lagbaja ni komari to ban jẹun èmi Lagbaja ni komari to ban rin lọ èmi Lagbaja ni komari ayafi to bafi oju kan mí'' ni ki ara è oto balẹ

Akiyesi!!
Ọjọ méje gbáko lao fi se isẹ yii sugbon lati ọjọ kẹta ní obinrin yi ati ma wawa kaa kiri ti aba wa ti pade pẹlu è kí adaa iṣẹ yí duro
Torípé isẹ́ yi leso di dindinrin.

17/11/2022

EYONU IFERAN GBOGBO AYE
Ewe oriji gbigbe, funfun Inu eso agbalumo, eso oju ologbo die, ewe Ola die, ao lo kuna, ao da sinu lofinda divine grace, ao da adi agbo die si, ao maa fi para jade.

Address

Ikere-Ekiti

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Eje Ka Jo Gbe Isese Laruge - Erinfolami posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share