25/09/2020
Aku ojumo gbogbo omo ile Ife okunrin obirin omode ati agba mo ki the imperial Royal Majesty OBA ogunwusi babatunde enitan adeyeye ooni risa arole oduduwa ooni of Ife pe aku odun olojo ti aun se lowo lowo yi emi wa ase pupo e tomo tomo ase edumare