Iranlowo Ewe Ati Egbogi

Iranlowo Ewe Ati Egbogi Iranlowo lati lo ewe ati egbo fun oniruru isoro to n doju ko eda.

13/04/2023

OSE AWORO TODAJU
Ewe Efin Rin, Ogiri, Asa Ti Won Ma Mun, Ao Gun
Gbogbo Re Papo Pelu Ose ,ao Le Ose Yi Mon Eyin Lekun
Inu Le Ao Mabuwe Lararo Kutu Kato Soro Si Eni Kan
Kan, Pelu Gbolohun Re, Firi Firi Ki Won Nile Elefinrin
Tolaye Esi Lekun Anu, Owo, Ola, Ire Gbogbo Fun Emi
Giri Giri Ki Da Nile Ologiri, Be Fun Mi Ta Fun Mi Ki Won
Nile Alasa, Bi Onile Batilekun Dandan Ni Kosi, Eyin
Lagbaja Omo Lagbaja Loni

13/04/2023

AROBI/ASETA
A o fi iso tuntun lu oju agbon kan,a o wa ko omo atare
42 si enu a o je kuna,a o mu omi agbon yen si pelu
adura pe gbogbo eni toban dimi lowo ise rere ki oro re
o dojuru,ti aba mu omi tan,a o fo agbon danu.

13/04/2023

.

Odidi agbado pupa kan, ao so sinu epo pupa, ao so oruka elelo meji mo lara, ao wa so agbado naa sí arin awon ijalo, ti ijalo bati bo daada, ao wafi inkan gbe agbado naa pelu awon ijalo tio wa lara re sinu agbada ijogun, ao wa jo gbogbo re, ao ro ebu re sinu igo kan, ao mafi oruka naa si owo.

:- ao wa da ebu naa luwon lara, won a side pada.

13/04/2023

OGUN ALAKALA
koriko iwaju ile ati eyin kule,botuje pupa tabi
funfun,odidi atare kan,ao jopo ao po mose,odi
wiwe,odaju gan.

15/10/2022

OGUN ATUDE
Egbo ako ibepe, ao ko sinu odo, ose dudu, ao wafi eyin ororo kan po dada, ao dasi ona meta, ao mafi epo pupa pa ara ki a to we ni alale fun ojo meta.

29/08/2022

ASOPO IFERAN OBINRIN TOGBONA DADA

Omolangidi tako tabo
Eyele funfun tako tabo
Ewe Ina die
Ewe Esisi tutu die
Ewe airagba die
Ewe mako die
Ewe oloyin die
ata ijosi die

SISE RE 👇

aoko omolangidi ati awon eyele yen soto,aowa jo awon
eroja toku yen po aolo kunna dada,aoro ebu na sinu igo kan,aowa bu iwonba ti abafe lo sinu efe owu akese aowe lowu dudu ati funfun aowa fi maker ko oruko okunrin sara ere okunrin aotun ko oruko obinrin sara ere obinrin aowa fi ikobere na sarin won aowa we lowu dudu ati funfun ti koni han mo Aowa pa eje eyele mejeji yi si lara ti yio mu dada leyin na aoso okun mo aolo gbeko lara igi kan nibi ti ategun yio tima fesi daada


AKIYESI PATAKI 👇

aoma di ikobere ebu toku diedie fun asopo lojo miran beeni aoma lo t**i yio fitan
Aolo ri awon eyele yen mole nibi tawon eyan ngba koja dada tobaje obinrin lo bewa nise asopo eyele abo ni yio wa ni isale koto eowa gbe ako si laya,tobaje okunrin lo bewa nise asopo,eyele ako ni yio wa ni isale koto eowa gbe abo si laya.
O Pari, Ina o moju e ni toda.

04/08/2022

OSE IWE ODO ISEGUN META TO SISE NI GBOGBO ONA

* Odindi Atare meta
* Ose to ba wu wa
* Kainkain ibile tuntun meta
* Epo pupa die

- A o yo gbogbo omo inu atare kookan ni otooto
- A o lo ni otooto
- A o wa po ebu atare kookan mo ose meteeta otooto
- A o fi si ara kainkain ibile tuntun meta otooto
A o ko awon kainkain ibile meteeta na lo si eti odo to n san ni arole patapata bi agogo mefa (6pm)
- Ti a ba fe we ni eti odo na, a o koko ma fi epo pupa para na ki a to we ose yen.

AKIYESI: A gbodo koko ka fi ma epo pupa para ki a to we ose na, be ni a o se we ose meteeta yen sinu odo to nsan.
Leyin iwe meteeta na, o le fe re wa die, e ma beru rara, sugbon e ma je ka lo oogun kankan. Leyin iseju die, ara wa ma bowa sipo pada.

OSE ASINA TI A O WE LEYIN IWE ODO ISEGUN YEN NIYI
* Ewe Ewuro 16
* Ewe Akoko 16
* Ata Ijosin gbigbe 16
* Ose to ba wu wa

- A o lo gbogbo awon eroja wonyen papo mo Ose
- A o ko ose na sinu Ike funfun Olomori kan

LILO RE: A o ma fi ose na we ni ale patapata laijade mo rara.

Ose ashina yi daju daadaa, tested and confirmed ni, mo ti nlo bo bi odun die seyin.

Fun ibeere 09032041680

18/07/2022

ASINA TON CONNECT EYAN

Ao wa ako alangba kan ao pa ao ki owo dollar si lenu ao fi sinu ape ao fi atare odidi kan si legbe ao wada eso iwerenjeje le.lori aojo ao mafi schnap loo laro laro..pelu ase olohun ao gba owo ao si connect maa n eniyan gidi.

10/06/2022

OGUN ITAJA TODAJU

Ori oka Kan
Ewe omisinmisin mejeji
Ewe eyin olobe oojo
Ewe alupaida oojo
Eyele ejigbede
Sisere
Aojo Ori oka yen nikan loto,aodi ebu re si ibikan, aowa gun ewe omisinmisin pelu alupaida loto, aowa po gbogbo re pelu ose dudu aowa pa eyele ejigbede, aofi eje awon eyele yen po oseyi dada aoko sinu igba tabi Ike funfun. aoma buwe lo ibi oja wa. ibiti oka bawa lonje re tinba.

ISE TI MO FE FI SILE YI, OLORUN NI MO FI BURA SI, ISE TO N JE BI IDAN NI. MO FE FI SILE NI ORUKO BABA MI NI, IWO TI O BA...
10/06/2022

ISE TI MO FE FI SILE YI, OLORUN NI MO FI BURA SI, ISE TO N JE BI IDAN NI. MO FE FI SILE NI ORUKO BABA MI NI, IWO TI O BA RI ISE YI KI O COMMENT PE OLORUN FI ORIJIN BABA MI NI ORUN.
MA SE FI ISE YI SE IJAMBA FUN OBINRIN O, NITORI PE TI ALO BALO, ABO N BO O.
ISE NAA RE O.
****OGUN TI OBINRIN BA SALO TI A SI FE KO PADA***
Iru ologesa kan, mariwo ope, sonso re, a o die ninu okuku alaso, eku ago kan, a o ko won si oju igbin apinnu kan, a o wa ri igbin naa mole, a o da oju igbin yen dele mo a won iyoku, a o ha yerepe die, a o po mo ori, ori yen ni a ofi tan ina fitila titun, a o gbe fitila naa sori ile ibi ti a ri igbin yen si.
Verse e. Iru oge ki jeki oge gbele, mariwo ope ki wo oju elomiran afi oluwa, lojukanna ti alaso joko si ni okuku wo to, akosin ki gbohun omo re ki o duro, igbin ki FI enu legi ki o ma gun, L-L , ni ki o wa pa ina yi. ODAJU. Obinrin naa ni yio wa pa ina naa.
E maa share re nitori awa okunrin ti won ti gba iyawo wa..

16/05/2022

Aseje Asina
A o wa Eran aguntan ao ge si ona 16 ao fi itannatonnagbowo ati iyere tabi ata ijosi ati epo iyo ao fise jeao fi iru naa si ao se Adura bi asenfe.

Address

Ilorin

Telephone

+2348150925157

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iranlowo Ewe Ati Egbogi posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Iranlowo Ewe Ati Egbogi:

Share