Chief Agunpopo Isegun Ogbomoso

Chief Agunpopo Isegun Ogbomoso Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Chief Agunpopo Isegun Ogbomoso, Business service, Babaisale compound Itapopo area Ogbomoso, Ogbomoso.

ISORI TODAJU Beere fun tie loni ola le peju
13/10/2025

ISORI TODAJU
Beere fun tie loni ola le peju

22/08/2025

Aku ojumo ninu Yara yi gbogbo ile aku ojo pipe ejagunmale yio tiwa leyin lase eledua Asheeeee waaaĆ aassaaaa.
Eje kia lo gbiyanju ise yi wo:;
ASEJE BIBO ASIRI TODAJU
ewe rere ako ati abo,ewe onitikuti to lalehu furare die,ewe ola die,ao lowon papo,ao fi din eyin Agric merin pelu ororo kuli tabi Ori,ao fi iyo obe die si,pelu iyere merindinlogun tabi ata ijosi merindinlogun (16).ao so si ori osuka to ba tutu ao daniyan owo NLA si ao koje.
Ijegun re:; Like and comment with your prayers Ona koni di mowa

OSE ASINA TODAJU DM ME FOR MORE DETAILS
03/10/2024

OSE ASINA TODAJU DM ME FOR MORE DETAILS

07/08/2024

Eyin Asiri ASINA TODAJU.Meta/merin loogun mosa koribe oluware kosa bi ologun se ni kosa ni.
ASIRI NA RE,,,,,,
Ewe AGOGO igun ti a npeni Ogbe akuko,ewe Bobo awodi,ewe ahun ti a npeni owe ahun,ao gun gbogbo re papo pelu ose eyikeyi,ao ko ose yi sinu igba olomori ao te ni ifa ejiogbe,ao pe gbolohun re si ,ao gbe pamo fun ojo meje,leyin ojo keje ao ma we ose yi losi bi oko owowa.
Gbolohun re:;Agogo igun ye igun afi fun igun, gbogbo omo araye ewa fi oore temi funmi Loni, Bobo awodi ye awodi,afi fun awodi, gbogbo omo araye ewa fi oore temi funmi Loni,owe ahun ye ahun afi fun ahun, gbogbo omo araye ewa fi OWO owoyin ra ojami/be emi lagbaja omo lagbaja nise,OBA ni ejiogbe laarin awon odu toku,Eleda mi wa semi loba lenu isemi.

Akiyesi;akogbodo si ose yiwo fun odidi ojo meje yen ooo.
Eledumare aje kio je fun gbogbo eni toba gbiyanju re.
Fun Ibeere Lori re,tabi omiran
Inbox me on Whatsapp
08165315047
Chief Agunpopo copy

10/07/2024
AWORO OKIKI TODAJU DM ME FOR URS
03/06/2024

AWORO OKIKI TODAJU DM ME FOR URS

OSE AANU TODAJU.call us for more details.08165315047
21/05/2023

OSE AANU TODAJU.call us for more details.08165315047

AGBA NI ETU,OMODE NI AWO
04/04/2023

AGBA NI ETU,OMODE NI AWO

Address

Babaisale Compound Itapopo Area Ogbomoso
Ogbomoso

Telephone

+2348165315047

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Chief Agunpopo Isegun Ogbomoso posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share