Adura ngba Ewe si nje. Eleda wa koni ko Ajo

Adura ngba Ewe si nje. Eleda wa koni ko Ajo Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Adura ngba Ewe si nje. Eleda wa koni ko Ajo, Sango Otta.

25/08/2020

Thanks 🙏 to all our lover in this page.
A question to all my of this page,
Should I create a WhatsApp for this same page for all the lover?

18/07/2020

Ose Atude
Ewe tude
Egbo tude
Irun ara Etu.
Ao lopo, ao fi Ose ko ni iwe e nkan soso.
Ao lowe si odo ton san dada.

Manage me this
06/05/2020

Manage me this

01/09/2019

Ibiti Mapa Wa Beena Ni Maji.
Ire Ni Hunse Hunko Nise Ika,ire Hunse Koni Di IBI Momi Lowo Lase Eledumare.
Amin Ashe...

17/08/2019

ASHINA ANU...
Ao Lo Ewe Omisinmisin Pelu Iyere Die,ao Fise Igbin Agbonu Meji,ao Se Lepo Niyo Ati Oyin Igan Die Si.
Ao Se Adura Si Ki Atoje

13/07/2019

Ejowo Mo Bee Gbogbo Ololufe Mi Ki Won Mase Binu Simi Aye Ni Kosi Funmi Repete.
ASEJE AWURE...
Omi Okun
Omi Osa
Ekiri Eran Elede Nla Kan
Ekiri Eran Malu Nla Kan
Ewe Sawerepepe Oojo Ati Ata Ijosi
Aseje Yi Dapupo Ni Ojo Aje(monday).

09/06/2019

EYONU AWON AGBA.
Afara Oyin
Ewe Ewo
Ewe Agbayun
Odindi Atare Kan.Ao Jo Papo,ao Lo Suga Onigun Merin Mo.
Ao Mafi Omi Lo.

09/06/2019

Aku Dede Ako koyi Asiku Aseku Odun Emiwa Yio Se O Po Re Ninu Alafia Tomotomo.
IMULE ~ASHINA
Eso Lara Pupa Ni Sale Ape Pelu Odindin Atare.Ao Da Ewuro Ojoo Bo Lori Ao Jo Papo.
Ao Mafi Oti Loni Alosun Ni Ale.
Ajuwase Abaramu.Amin Ase

02/03/2019

Adua Fun Ojo Ibi Eni(birth)
Alaumo Soli Alamuhamodiwaselim
Yah Alau~2000
Yah Adi~3000
Yah Muliku~ 4000
Yah Salam~ 5000
Yah Koaru~ 3000
Yah Kafi~ 4000
Yah Aleem~ 4000
Yah Lateef~1000
Yah Aleemu~3000
Yah Ayu ~ 3000
Yah Somodu~4000.
Ao Mase Adua Ni Ojo Kokan Fun Ojo Mokanla,Fun Iwo Ti O Komo Ojo Ibire Bere Adua Ni Ojo Aje(monday).Ki O Fi Beere Ohun Ti Ofe Lowo Olohun, Ekan Lodun Nio.

27/01/2019

Aku Alale Asiku Isinmi Oni O
Moni Ebun Kan Fun Enikeni Meji Akoko Ti O ba Beere Ogun Kogun Tobafe Larin Iseju Marun Timo Ba Post Yi Tan.
Ikilo Ibe Re,
Ma Beere Awon Ogun Wonyi
Ogun Owo
Ati Ogun Amudo,ranti Pe Obimo Abi Oma Bi Omo Lojo Kan.

14/01/2019

OGUN ANASARE.

Omo Ejo Osa Kan Lojo Ti Abapa,ao Wa Fi Odidin Atare Kan Si,ewe Aluro,ewe Ina.
Ao Jopo Mo Rawon Ti Asi Ran Ni Igbadi.

Address

Sango Otta

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Adura ngba Ewe si nje. Eleda wa koni ko Ajo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Adura ngba Ewe si nje. Eleda wa koni ko Ajo:

Share