17/10/2021
AMORAN PATAKI YI WA FUN AWON ONISOWO KARA-KATA ATI AWON ONILE ISE ALADANI BI SUPERMARKET, PHARMACY, DISTRIBUTORS, PETROL STATIONS ATI BEEBE LO.
Iwadi ijile fi mule wipe awon nkan marun yi se pataki fun Ile Ise ati okowo ti o ngbero lati gberu ( paapa awon ile ise ti aladani).
1.) Akosile kikun lori oja ti a nta jade ati eyi ti a nra wole pelu ayewo ati isiro lori won.
2.) Ayewo ati isiro to peye lori awon oja ti a ni lori igba lekankan lati mo boya won pe (o kere t**i laarin osu meta-meta si ara won.
3.) Mimu edinku ba owo oja ti a npa wole ti o nfi igbagbogbo din tabi sonu lati owo awon osise ti a gba sise.
4.) Siso ati sise akiyesi owo isuna ojojumo lenu okowo ti a nse( ti o ma nsaba se ifaseyin ati akoba fun ere ti ile ise nje.
5.) Ni ipari (ti o si se pataki julo), sise amulo awon akosemose nipa akoso ile ise ati isiro owo ( fun ijiroro ati amojuto - paapa lori eto eyawo fun idagbasoke okowo wa ).
Isiti yi wa lati ile ise EMKAY GLOBAL KONSULT & BUSINESS SOLUTION ti office won wa ni 2nd floor, Yalogs paints house, ljemo Agbabdu, Abeokuta.
Tel. Nos: 09057572323, 08067746953 or 09032063654.
Email: samkolmasco@
Latest news coverage, email, free stock quotes, live scores and video are just the beginning. Discover more every day at Yahoo!