15/08/2026
❓ FAQ CAC #7
ṢÉ CAC CERTIFICATE MÁA Ń EXPIRE?
Ọ̀pọ̀ oníṣòwò máa ń béèrè pé:
CAC Certificate mi máa ń expire ni?
Ìdáhùn ni pé, Certificate CAC fúnra rẹ̀ kì í kan expire nítorí pé ọ̀pọ̀ ọdún ti kọjá lórí ẹ
Ṣùgbọ́n èyí kò túmọ̀ sí pé o lè forúkọsílẹ̀ lẹ́ẹ̀kan, kí o sì gbàgbé gbogbo ọ̀rọ̀ compliance.
Lẹ́yìn registration, àwọn ojúṣe kan tún wà tí oníṣòwò gbọ́dọ̀ máa ṣe, gẹ́gẹ́ bí Annual Returns àti àwọn ìmúdójúìwọ̀n tó bá kan business rẹ.
📌 Nítorí náà: Registration kì í ṣe òpin — compliance ni ó ń jẹ́ kí business rẹ wà ní ìlànà ti òfin.
Ṣé o ti ṣàyẹ̀wò compliance status business rẹ lọ́dún yìí?
📩 DM wa pẹlu "CHECK" kí a lè ràn ọ́ lọ́wọ́.
̀rànÒwòNíYorùbá