13/08/2023
ISEYI WA FUN GBOGBO AWON OMO OLOGO TIKO RI OGO YEN LO..
OPOLOPO AWON EYAN LOWA NINU AYE TOJE WIPE WON TI LO KADARA WON TI WON KOSI MO,, WON KAN SISE BI ERIN LASAN NI KOSI AYIPADA KANKAN,, AWON ONA TI AYE LE GBA LATI GBA KADARA EYAN O POO LORISIRISI..
GBOGBO EYAN TIWON NPE NI OMO OLOGO GBOGBO WON KO LONI OGO MO WON TI GBA TI ELOMI... TORI E NI OMO ELERAN ELOMI FI JE EGUNGUN..
ISENA RE:- Tio bafe kosise fun o daada koko share re si opolopo group kio si comment si sale re.. Ao lo wa ewe lapapa funfun eyo meta pere pelu obi eyo kan ati ose iwe ti ale fi we lekansoso, ao wa gun ewe yi ati obi yi papo dada ti o ba ti kuna ao wa gun ose yen na papo mon ao wa lofi ose yen we ni ale akoko fi epo pupa pa ara wa dada ao wa fi ose yen we. ayafi tiko ba si Olorun mon sungbon ti Olorun ba wa mo bura lati ojo yen ona kotun di mon wa mon gbogbo inkan wa ni yoma lo dede ti Owo yosi ma wole fun wa ni irorun yowa dapi igba pe Ile aye yi Koni awa tele ni. Ao ri ogo wa loo..
ENITI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MA BI O FESE KIO Pemi ((08104333723)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE..